Àdùkẹ́ ń gbé pẹ̀ lú àwọn òbí òbí rẹ̀ ní ìlú Ìbàdàn, Ìyá Àgbà ló sì fẹ́ràn jùlọ lágbàáyé.Ó fẹ ́ràn kí Ìyá Àgbà máa kọrin fún àti bí wọ́n ṣe máa ń fun ní kókóró láti inú ìsọ̀ wọn.Ní ọjọ́ kan, Àdùkẹ́ dé láti ilé-ìwé, ṣùgbọ́ n kò rí Ìyá Àgbà níbì kankan! Àdùkẹ́ ò mọ ìdí tíÌyá Àgbà ò l..
Kwashiorkor is a common nutritional disease found among children in developing countries. It commonly causes swollen stomachs and bodies, fluffy, discoloured hair, and weeping wounds among children who are poorly weaned off breastmilk.1In this Medi-Tale, Ayọ̀mídé champions a mission to help little À..