Menu
Your Cart

Aduke Iya Agba ati Asiri Osupa by Jumoke Verissimo and Chinyere Okoroafor - Paperback

Aduke Iya Agba ati Asiri Osupa by Jumoke Verissimo and Chinyere Okoroafor - Paperback
Aduke Iya Agba ati Asiri Osupa by Jumoke Verissimo and Chinyere Okoroafor - Paperback
N5,500
Ex Tax: N5,500
  • Stock: In Stock
  • Model: Picture Book
  • Weight: 0.90kg
  • ISBN: 9781913175382

Àdùkẹ́ ń gbé pẹ̀ lú àwọn òbí òbí rẹ̀ ní ìlú Ìbàdàn, Ìyá Àgbà ló sì fẹ́ràn jùlọ lágbàáyé.

Ó fẹ ́ràn kí Ìyá Àgbà máa kọrin fún àti bí wọ́n ṣe máa ń fun ní kókóró láti inú ìsọ̀ wọn.

Ní ọjọ́ kan, Àdùkẹ́ dé láti ilé-ìwé, ṣùgbọ́ n kò rí Ìyá Àgbà níbì kankan! Àdùkẹ́ ò mọ ìdí tí

Ìyá Àgbà ò le padà wá mọ́. Nígbà náà ni àntí Yímíká sọ àṣírí kan fún.

Ṣé lóòótọ́ ni ó lè rí Ìyá Àgbà nínú òṣùpá tí ó bá ṣe ojú rẹ̀ tínńtín?

Write a review

Note: HTML is not translated!
Bad Good